Verse 1
(9ice)
Ojo rebi ana gb'ominira,
1960
N'igba yen t'is easy
gege bo se wi
Ta rugbo, t'omidan lon duru
ba ti'n d'ominira
Omi inira indeed abi, ewo
naira wa
llu polukulumushu
T'ewe t'agba lon j'eyan won
nisu
abe ori, ewe eri, sugbo e
ofewi
abe ori, agba eri atenuje
lofe p'ayin
petepete t'ana ni popa
eni bataba, kolo mofe ni
Chorus
sebe l'ema suun
teba sope 'omo nkankan
eyin aro lema waa (sebe la
maa)
mewa n'sele o
sebe l'ema suun (sebe lema
sun un)
eni wo seju akan o
eyin aro lema waa (mewa
nsele o)
Verse 2
(Asa)
kini suuru tio l'ere
kini seti ko s'ere
won sa l'eyan tio l'oruko
okuku sise, ode'n rere e
Aah ede s'ope a siwa
l'omode
nkan sa l'eye je k'agbado
t'ode
9ice oro gidi l'oso
an'lati fi laka y'esi
k'asoro sibi t'orowa
Chorus
sebe le masun oo (sebe le
masuun un)
eyin aro l'ema wa a (sebe
l'ema sun un)
mewa n'sele o (sebe l'ema
sun un)
eyin aro, eyin aro lema wa
(teba aro lema wa o (mewa
nsele o)
Verse 3
(9ice)
oda siko bo yen
won wa s'adugbo
won a'somo je eje
eje kan wole tan
gbogbo eje tan je da w'oke
ise
toba tun se were, la siko
won ani k'ado tolo bere
won a senu mere, kalokalo
gbe nkan mi senu uye
(Kalo kalo gbe...)
afira aditu ti iwole
talo dibo fun un
pasan ta fi na yale
onbe lori aja fun un un
odo elo tunramu,
ema je an'pagbon ni funfun
fun yin
mowi temi ii
Verse 4
(Asa)
Asegbe kan kosi oo
Asepamo lowa
Ase s'ile labo waba
Emi oti iku, mo s'ile s'ile
Mo sile f'owo r'ewo
Mo sile tule mise iiiii
Chorus
sebe l'ema sun un
teba sope o'mo nkankan
eyin aro lema wa a
mewa nsele o
sebe le na sun un
eni w'oseju akan o
eyin aro l'ema waa
sebe le maa (mewa n'sele o
ooooo
l'ema sun un (4x)
sun un
9ice - Pete Pete Lyrics
Africa Music Lyrics
( If you find errors and need to make corrections, pls submit Here )