RUZRIC.com
A. B. C. D. E. F. G. H. I. J. K. L. M. N. O. P. Q. R. S. T. U. V. W. X. Y. Z. 0-9.

 
 
Name: Da Grin
Song title: Ni 94 Lyrics

Chrous
Amogba ti bukkky wa ni
primary 4
ni 94, nigba t'oshi ma nwo
pinafor
gbogboy yen itan ma ni yen
bukky ti d'omoge mo wa
l'owo

Verse 1
mo ranti 'gba ti bukky shi wa
ni pry4
ni 94, nigba t'sh ma n wo
pinafor
ni kekere, owun pelu
yewande
awon omo yen ma ti d'agba
gan nsinyin,
o ranti igba ti a ma nko won
lo si jeleosinmi
awon na ti njo sean paul
ninu club
shebi mummy won lo wa
nibikan tiwon tinshe robb
ni egbe aboki kan to ma n
sun sinu shop
eh! eh! awon omo yen ma ti
d'omoge o
mo pe bukky lana o so funmi
pe sege
leke o ranti awon omo yi tey

tey
omo f'orole, na today?
e don tey, awon omo ti won
ma nfi yepe sere panti
ki won to ji laaro, won a ti to
sori eni
awon mummy won ma ni
kingbe won lo s'odo nanny
sugbon won ti d'agba
nisinyin won fe mo mi
(Repeat Chorus)

Verse 2
O ranti emi boda korede ni
keker?/
o ranti gbogbo igba ti e shi
maa n fi iyepe sere
ni ojo sunday sunday mo
maa n fun gbogbo yin ni fere
dakun ma ni o momi mo
ma f'agba sere, o ti e ni ore
kan ti won maa n pe ni titi
titi shi ranti gbogbo igba ti
mo wa n fun yin ni
shin shin mo ri titi lana
gbogbo ori mi mi tititi/ mo ni
Olohun gba mi gbogbo yin
leti di sisi
ni 94, nigba t'oshi wa ni
primary2
e fe se party ni school, o
ni fe ko shoe
nitori ti e, mummy e ranmi
lo coutonou
mo wa soro nisinyin, o wa
ni kin me shuonu
iwo to jepe o maa n fi iyepe
sere panti
ki o to ji laaro, wa ti to s'ori
eni
awon mummy e ma ni
kingbe e lo si odo nanny
sugbon o ti dagba nisinyin

Da Grin - Ni 94 Lyrics

Africa Music Lyrics

( If you find errors and need to make corrections, pls submit Here )